click below
click below
Normal Size Small Size show me how
Ẹbi Mi
questions/answers
| Question | Answer |
|---|---|
| Ṣé o ní àbúrò? | Rárá, mi ò ní àbúrò |
| Ṣé o ní òrẹkunrin? | rara, mo ni orebinrin |
| So fo mu ni pa ebi | mo ni baba ati mama. mo ni egbon kan |
| kini oruko mama e? | oruko mama mi ni Yuko |
| kini oruko baba e? | oruko baba mi ni Jun |
| kini oruko egbon e? | oruko egbon mi ni Kotaro. |
| kini oruko e? | oruko mi ni Sawa |
| se o ni iyawo? | beeni, mo ni iyawo |
| kini oruko iyawo e? | oruko iyawo mini Heidi |
| omo orile-ede wo ni e? | om orile-ede Amerika ati Japan ni mi |
| Nibo ni won bi e si? | Won bi mi si ilu Miyoshi ni ipinle Aichi |
| Se o gbo Yoruba? | Mo gbo Yoruba die |
| Kini o feran lati Ṣe? | Mo feran lati luwee |
| Kini o ko feran lati se? | N ko feran lati gba boolu |
| Ise wo ni Baba ń se? | Baba mi je onimo-ero |
| Kini baba e feran lati se? | Won feran lati gba goofu |
| Kini o máa se ni opin ose? (What will you do at the end of the week) | Mo máa se ise amurele. Mo sì máa sùn (I will do my homework and i will sleep) |
| How do you say "I will do my homework" | Mo máa se ise amurele |
| How do you say "I will cook" | Mo máa dáná |
| Bawo ni a se n soo "I will watch a movie" | Mo máa wo fíìmù |
| Bawo ni a se n soo "I will read a book" | Mo máa ka ìwé. |
| Bawo ni a se n soo "what do you not like to do" | Kini o ko feran lati se? |
| Bawo ni a se n soo "what do you like to do" | Kini mo feran lati se? |
| Bawo ni a se n soo "I will go to Indianapolis" | "Mo maa lo si Indianapolis" |